Èdè jẹ́ ọ̀nà kan tí à ń gbà bá ara wa sọ̀rọ̀. Ọpẹ́yẹmí (2015:21) ṣàlàyé pé èdè ni ariwo tí ó ti ẹnu àwa ènìyàn jáde tí ó ní ìtumọ̀, tí ó ní iṣẹ́ láti jẹ́ fún ẹni tí ó gbọ́ ọ, tí ó ní ìlànà kan pàtó tí àwọn elédè ń tẹ̀lé, tí ó sì jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà fún gbogbo àwọn olùsọ èdè náà. Èdè ni òpómúléró fún iṣẹ́ lítíréṣọ̀, láì sí èdè, kò lè sí àtiwáyé iṣẹ́ lítíréṣọ̀. Oríṣiríṣi ọ̀nà ni àwọn elédè ń gbà mú èdè wọn rẹwà yálà ní sísọ lẹ́nu tàbí nínú kíkọ sílẹ̀. Gbogbo àwọn èdè tó gbajú-gbajà ní àgbáyé bí Èdè Gẹ̀ẹ́sì, Faransé, Potogí, Lárúbáwá, Swàhílì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ló ní àwọn ọnà amédè-rẹwà fún afọ̀. Èyí kò sì yọ èdè Yorùbá sílẹ̀. Àwọn ìpèdè bẹ́ẹ̀ ni àwọn onímọ̀ pè ní àwọn “Ọnà-èdè", wọ́n sì máa ń mú kí afọ̀ Yorùbá kún fún ìmọ̀, ìtumọ̀ àti òye. Irúfẹ́ àwọn ìpèdè bẹ́ẹ̀ yàtọ̀ sí èdè ṣákálá tàbí àsọ̀jẹ ọ̀rọ̀ lásán. Àwọn ìpèdè yìí dúró gẹ́gẹ́ bí òpó fún afọ̀. Àwọn òpó wọ̀nyí ni àwọn Gẹ̀ẹ́sì pè ní “Figures of Speech”. Èyí fihàn pé gbogbo èdè ló ní tirẹ̀. Orúkọ tí èdè kọ̀ọ̀kan ń pe tirẹ̀ ló yàtọ̀. Ọnà-èdè ni àwọn hóró ọ̀rọ̀ tàbí àwọn ìpèdè tí aṣafọ̀ múlò láti mú adùn wọ afọ̀ rẹ̀, oríṣiríṣi sì ni àwọn ọnà-èdè tí a ní nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni òwe, àkanlò-èdè, àwítúnwí, àsọrégèé, ìfọ̀rọ̀dárà, ìfìrósínròjẹ, Ìbádọ́gba gbólóhùn, àfiwé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Table of Contents
1.0 Ìfáàra
1.1 Èrèdí Ìwádìí
1.2 Èròngbà Ìwádìí
1.3 Ìwúlò Iṣẹ́ Ìwádìí
1.3 Ọgbọ́n Ìwádìí
1.5 Ibi Tí Ìwádìí Yóò Gbòòrò Dé
1.6 Ètò Ìwádìí
1.5 Ìtàn Ìgbésí Ayé Óládẹjọ Òkédìjí
2.0 ÌFÁÀRÀ
2.1 ÈRÒ ÀWỌN ONÍMỌ̀ NÍPA ÈDÈ
2.2 ÌBÁṢEPỌ̀ LÁÀRIN ÈDÈ ÀTI ÀṢÀ
2.3 ÈRÒ ÀWỌN Ọ̀MỌRÀN NÍPA LÍTÍRÉṢỌ̀
2.4 ÈRÒ ÀWỌN ONÍMỌ̀ NÍPA ÌBÁṢEPỌ̀ TÓ WÀ LÁÀRIN LÍTÍRÉṢỌ̀ ÀTI ÈDÈ
2.5 ÈRÒ ÀWỌN ONÍMỌ̀ NÍPA ÌBÁṢEPỌ̀ TÓ WÀ LÁÀRIN LÍTÍRÉṢỌ̀ ÀTI ÀWÙJỌ
2.6 PÀTÀKÌ ỌNÀ-ÈDÈ NÍNÚ IṢÉ LÍTÍRÉṢỌ̀
2.7 ÀKÀNLÒ-ÈDÈ GẸ́GẸ́ BÍ Ọ̀KAN LÁRA ÈRÒJÀ LÍTÍRÉṢỌ̀
2.8 Iṣẹ́ Òkédìjí
2.9 TÍÓRÌ ÌṢÀMÚLÒ: TÍÓRÌ ÌFOJÚ ÌHUN-TÍ-O-SO-PỌ̀-MỌ́-ÌṢÈLẸ̀ ÀWÙJỌ
3.0 Ìfáàra
3.1 ÀWÙJỌ TÓ BÍ ÌWÉ ÌTÀN ÀRÒSỌ ÒKÉDÌJÍ
3.2 Ìsọníṣókí ìwé ìtàn àròsọ Àjà ló lẹrù àti Àgbàlagbà Akàn
3.3 ÀWÙJỌ NÀÌJÍRÍÀ ÀTI ÌWÀ Ọ̀DARÀN
3.4 OKÙNFÀ ÌWÀ Ọ̀DARÀN NÍ ÀWÙJỌ YORÙBÁ BÍ Ó ṢE HÀN NÍNÚ ÀJÀ LÓ L’ẸRÙ ÀTI AGBÀLAGBÀ AKÀN
3.5 ÌSỌ̀RÍ ÌWÀ Ọ̀DARÀN
3.6 IPA ÌWÀ Ọ̀DARÀN LÁWÙJỌ
3.7 ÀBÁ ÒKÉDÌJÍ FÚN DÍDÉKUN ÌWÀ Ọ̀DARÀN LÁWÙJỌ
3.7.1 OJÚṢE ÌJỌBA
3.7.2 OJÚṢE ÀWỌN ỌLÓPÀÁ
3.7.3 OJÚṢE ÀWỌN ÒBÍ
3.8 ÌFÌWÀWẸ̀DÁ NÍNÚ ÌWÉ ÌTÀN ÀRÒSỌ ÀJÀ LÓ LẸRÙ ÀTI ÀGBÀLAGBÀ AKÀN
3.8.1 Ọgbọ́n tí Òkédìjí lò láti fi ṣe ẹ̀dá inú ìtàn
4.0 ÌFÁÀRÀ
4.1 ÀKÀNLÒ-ÈDÈ ONÍHUN ẸYỌ Ọ̀RỌ̀
4.2 ÀKÀNLÒ-ÈDÈ ONÍHUN AWÉ GBÓLÓHÙN
4.3 ÀKÀNLÒ ÈDÈ ONÍHUN ÀPÓLÀ ÌṢE
4.4 ÀKÀNLÒ-ÈDÈ ONÍHUN ODIDI GBÓLÓHÙN
4.5 ÌPÍNSÍSỌ̀RÍ ÀKANLÒ-ÈDÈ TÍ ÒKÉDÌJÍ LÒ LÓRÍ KÓKÓ TÍ WỌ́N DÁLÉ LÓRÍ
4.5.1 ÀWỌN ÀKANLÒ-ÈDÈ TÓ DÁ LÓRÍ OÚNJẸ
4.5.2 ÀKANLÒ-ÈDÈ TÓ JẸMỌ́ Ẹ̀SÌN
4.5.3 ÀKANLÒ-ÈDÈ TÓ JẸ MỌ́ ẸRANKO
4.5.4 ÀKÀNLÒ-ÈDÈ TÓ BÁ Ẹ̀YÀ ARA ÈNÌYÀN LỌ
4.6 ÌLÒ ÈDÈ NÍNÚ ÌWÉ ÌTÀN ÀROSỌ ÀJÀ LÓ LẸRÙ ÀTI ÀGBÀLAGBÀ AKÀN
5.0 ÌFÁÀRÀ
5.1 ÌSỌNÍṢÓKÍ ÀBÒ ÌWÁDÌÍ
5.2 ÀMÚYẸ ÀTI ÀLÉÉBÙ IṢẸ́ ÀKÀNṢE YÌÍ
5.3 ÌMỌ̀RÀN FÚN ÌWÁDÌÍ ỌJỌ́ IWÁJÚ
5.4 ÌKÁDÌÍ
Research Objectives & Topics
The main objective of this study is to analyze the use of idioms and linguistic stylistic devices in the novels "Àjà ló lẹrù" and "Àgbàlagbà Akàn" by Oládẹjọ Òkédìjí. The study seeks to uncover how these linguistic structures contribute to the narrative, the author’s intent, and the sociolinguistic depiction of Nigerian society.
- Analysis of idioms and metaphorical language in Yoruba literature.
- Application of Genetic Structuralism theory to interpret literary texts.
- The relationship between language, culture, and society in the selected novels.
- Exploration of social issues and crime as depicted by the author.
- Evaluation of the role of law enforcement and social responsibility in the narratives.
Excerpt from the Book
Àjà ló lẹrù
Ìtàn náà bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Lápàdé olú ẹ̀dá ìtàn tí ó ń ti oko bọ̀ padà sí Ìbàdàn. Ó ń ronú lórí bí ìwà ọ̀daràn ṣe ń gbilẹ̀ sí ní ìlú Ìbàdàn. Ó gbọ́ tí nǹkan ń dún nínú igbó, ó sì tọnpinpin rẹ̀ títí ó fi rí owó bàntùbantu kan wú jáde níbi tí ẹnìkan rì í mólẹ̀ sí. Ó pàdé Áúdù Kàrímù, ìyẹn ọ̀gá ọlọ́pàá lójú ọ̀nà bákan náà. Áúdù sì rò, ó kò fun nípa bí àwọn ọ̀daràn ṣe mú iṣẹ́ le fún àwọn ọlọ́pàá tí àwọn ènìyàn sì ń rò pé àwọn ọlọ́pàá kò mọ iṣẹ́ wọn ṣe.
Ibè ni Áúdù ti le onímọ́tò kan tí ó ń sáré àsápajúdé tí Lápàdé sì gbọ̀nà rẹ̀ lọ. Onímótò tí Áúdù lé lọ tún padà wá láti wá kọlu Lápàdé ṣùgbọ́n ó kùnà, ọkọ̀ náà sì forí lu igi. Lápàdé gbé awakọ̀ náà kúrò nínú ọkọ̀, ó sì sọ ọ́ mọ́ igi sínú igbó, lẹ́yìn èyí ni Lápàdé padà sí ilé rẹ̀.
Chapter Summary
1.0 Ìfáàra: This chapter provides an introduction to the research, defining the scope, purpose, and significance of the study concerning idiomatic usage in literature.
2.0 ÌFÁÀRÀ: This chapter reviews literature and theories related to the nexus between language, culture, society, and the role of figurative language in literature.
3.0 Ìfáàra: This chapter conducts an in-depth analysis of the themes in the selected novels, focusing on social issues such as crime, law enforcement, and the author's proposed solutions.
4.0 ÌFÁÀRÀ: This chapter categorizes and examines the linguistic idioms found in the novels, applying specific theories to analyze their structural and semantic properties.
5.0 ÌFÁÀRÀ: The final chapter summarizes the research findings, highlights the study's implications, and offers suggestions for future investigations.
Keywords
Yoruba literature, Oládẹjọ Òkédìjí, idiomatic language, linguistic analysis, social criticism, crime fiction, cultural identity, Genetic Structuralism, sociolinguistics, proverbs, narrative structure, stylistic devices, social responsibility.
Frequently Asked Questions
What is the core subject of this research?
The research explores the sophisticated use of idioms and stylistic devices in the Yoruba novels of Oládẹjọ Òkédìjí, specifically within the social context of his crime novels.
What are the primary themes explored?
The study focuses on the intersection of language and society, analyzing how the author critiques social decadence, crime, and the effectiveness of law enforcement in Nigerian society.
What is the primary objective of this study?
The objective is to fill the academic gap regarding the systematic analysis of idiomatic expressions in Òkédìjí’s works and to determine their role as a social commentary tool.
Which scientific methodology is employed?
The study employs the theory of Genetic Structuralism, combined with sociolinguistic perspectives, to analyze the structure and social implications of the language used in the novels.
What is discussed in the main body?
The main body examines the relationship between language and society, the stylistic categorization of idioms, and how the author reflects societal ills to suggest moral corrective measures.
What key terms characterize this research?
The research is characterized by terms such as Yoruba literature, idiomatic expressions, sociolinguistics, social criticism, and crime narrative.
How does the author reflect the society of the 1960s?
Through the behavior of characters and criminal activities depicted in the novels, the author mirrors the economic and political instability in Nigeria during that period.
Why does the research analyze "Àjà ló lẹrù" and "Àgbàlagbà Akàn"?
These specific novels are chosen because they offer a dense and rich dataset for examining idioms in the context of police narratives and social justice struggles.
What is the role of language in Òkédìjí's works according to this study?
Language serves as an essential tool for artistic expression and as a semiotic signifier for social values, reflecting both the wisdom and the moral conflicts of the Yoruba society.
- Arbeit zitieren
- Jacob Gbenga (Autor:in), 2017, Ìlò Àkànlò èdè nínú Àwọn Ìwé Ìtàn Àròsọ Ọladẹ̀jọ Òkédìjí, München, GRIN Verlag, https://www.grin.com/document/434477